Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì wí fún un pé, “Ìwọ ń ṣe òmùgọ̀!” Ṣùgbọ́n ó tẹnumọ́ ọn gidigidi pé bẹ́ẹ̀ ni sẹ́. Wọn sì wí pé, “Ańgẹ́lì rẹ̀ ni!”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:15 ni o tọ