Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nígbà tí ó sì rí i, ó mú un wá sí Áńtíókù. Fún ọdún kan gbáko ni wọ́n fi ń bá ìjọ péjọ pọ̀, tí wọ́n sì kọ́ ènìyàn púpọ̀. Ní Áńtíókù ni a sì kọ́kọ́ ti pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn ni “Kírísítìánì.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:26 ni o tọ