Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà ti ó dé ti ó sì rí ẹ̀rí oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run, ó yọ̀, ó sì gba gbogbo wọn níyànjú pé, pẹ̀lú ìpinu ọkàn ni kí wọn fi ara mọ́ Olúwa.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:23 ni o tọ