Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì sọ fún wa bí òun ti rí ańgẹ́lì kan tí ó dúró ní ilé rẹ̀, tí ó sì wí pé, ‘Ránṣẹ́ lọ sí Jópà, kí ó sì pe Símónì tí àpèlé rẹ̀ jẹ́ Pétérù;

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:13 ni o tọ