Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olùfọkànsìn, àti ẹni ti ó bẹ̀rù Ọlọ́run tilé tilé rẹ̀ gbogbo, ẹni tí ó ń tọrẹ àánú púpọ̀ fún àwọn ènìyàn, tí ó sì ń gbàdúrà sọ́dọ̀ Ọlọ́run nígbà gbogbo.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:2 ni o tọ