Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Pétérù sì ti ń dààmù nínú ara rẹ̀ bí a ìbá ti mọ̀ ìran tí oun ri yìí sí, si wò ó, àwọn ọkùnrin tí a rán wá láti ọ̀dọ̀ Kọ̀nélíù dé. Wọ́n ń bèèrè ilé Símónì, wọ́n dúró lẹ́nu ọ̀nà.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:17 ni o tọ