Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ láti ìgbà bamitíìsì Jòhánù títí ó fi di ọjọ́ náà ti a gbe é lọ sókè kúrò lọ́dọ̀ wa. ó yẹ kí ọ̀kan nínú àwọn wọ̀nyí ṣe ẹlẹ́rìí àjíǹde rẹ̀ pẹ̀lú wa.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:22 ni o tọ