Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì wí pé, “Ẹ̀yin ara Gálílì, è é ṣe tí ẹ̀yin fi dúró tí ẹ̀ ń wo ojú ọ̀run? Jésù yìí, tí a gbà sókè ọ̀run kúrò lọ́wọ́ yín, yóò padà bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹ ti rí tí ó ń lọ sì ọ̀run.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:11 ni o tọ