Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gálátíà 6:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ará, bí a tilẹ̀ mú ẹnìkan nínú ẹ̀sẹ̀ kan, kí ẹ̀yin tí í ṣe ti Ẹ̀mí mú irú ẹni bẹ́ẹ̀ bọ̀ sípò nínú ẹ̀mí ìwà tútù; kí ìwọ tìkárarẹ̀ máa kíyèsára, kí a má baà dán ìwọ náà wò pẹ̀lú.

Ka pipe ipin Gálátíà 6

Wo Gálátíà 6:1 ni o tọ