Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gálátíà 5:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí a ti pè yín sí òmìnira, ará kìkì pé kí ẹ má ṣe lo òmìnira yín bí àǹfààní sípa ti ara, ṣùgbọ́n ẹ máa fi ìfẹ́ sin ọmọnìkejjì yín.

Ka pipe ipin Gálátíà 5

Wo Gálátíà 5:13 ni o tọ