Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gálátíà 4:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀, nígbà tí ẹ̀yin kò tí i mọ Ọlọ́run, ẹ̀yin ti sìnrú fún àwọn tí kì í ṣe Ọlọ́run nípa ẹ̀dá.

Ka pipe ipin Gálátíà 4

Wo Gálátíà 4:8 ni o tọ