Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gálátíà 3:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣé Ọlọ́run fún yín ní Ẹ̀mí rẹ̀, tí ó sì ṣe iṣẹ́-ìyanu láàrin yín nítorí tí ẹ̀yin pa òfin mọ, tàbí nítorí ẹ ní ìgbàgbọ sí ohun tí ẹ gbọ́?

Ka pipe ipin Gálátíà 3

Wo Gálátíà 3:5 ni o tọ