Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gálátíà 3:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yin aláìnírònú ará Gálátíà! ta ní ha tàn yín jẹ, kí ẹ̀yin má ṣe gba òtítọ́ gbọ́? Ní ojú ẹni tí a fi Jésù Kírísítì hàn gbangba láàrin yín ni ẹni tí a kàn mọ́ àgbélébùú.

Ka pipe ipin Gálátíà 3

Wo Gálátíà 3:1 ni o tọ