Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gálátíà 1:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí àwa ti wí ṣáájú, bẹ́ẹ̀ ni mo sì tún wí nísinsinyìí pé: Bí ẹnìkan bá wàásù ìyìn rere mìíràn fún yín ju èyí tí ẹ̀yin tí gbà lọ, jẹ́ kí ó di ẹni ìfibú títí láéláé!

Ka pipe ipin Gálátíà 1

Wo Gálátíà 1:9 ni o tọ