Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gálátíà 1:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì ta ọ̀pọlọ́pọ̀ àwọn ẹlẹgbẹ́ mi yọ nínú ìsìn àwọn Júù láàrin àwọn ìran mi, mo sì ni ìtara lọ́pọ̀lọpọ̀ sì òfin àtọwọ́dọ́wọ́ àwọn baba mi.

Ka pipe ipin Gálátíà 1

Wo Gálátíà 1:14 ni o tọ