Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Éfésù 4:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ẹni tí ń jalè má ṣe jalè mọ́: ṣùgbọ́n kí ó kúkú máa ṣe làálàá, kí ó máa fi ọwọ́ rẹ̀ ṣiṣẹ́ ohun tí ó dara, kí òun lè ní láti pín fún ẹni tí ó ṣe aláìní.

Ka pipe ipin Éfésù 4

Wo Éfésù 4:28 ni o tọ