Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Éfésù 4:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ọ̀dọ̀ ẹni ti ara náà tí a ń so ṣọ̀kan pọ̀, tí ó sì ń fi ara mọ́ra, nípaṣẹ̀ oríkèé kọ̀ọ̀kan tí a ti pèsè, nígbà tí ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan bá ń ṣiṣẹ́ dáradára, yóò mú ara dàgbà, yóò sì gbé ara òun tìkárárẹ̀ dìde nínú ìfẹ́.

Ka pipe ipin Éfésù 4

Wo Éfésù 4:16 ni o tọ