Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Éfésù 1:5-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. ni Ó ti yàn wá tẹ́lẹ̀ sí ìsọdọmọ nípa Jésù Kírísítì fún ara rẹ̀, ní ìbámu ìdùnnú ìfẹ́ rẹ̀

6. fún ìyìn ogo oore ọ̀fẹ́ rẹ̀, èyí tí Ó ti fi fún wa nínú Àyànfẹ́ rẹ̀:

7. Nínú rẹ̀ ni àwa ni ìràpadà wa nípa ẹ̀jẹ̀ rẹ̀, ìdáríjì àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa, ní ìbámu pẹ̀lú ọrọ̀ oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run

8. èyí tí ó ya lù wá pẹ̀lú gbogbo ọgbọ́n àti ìmòye,

Ka pipe ipin Éfésù 1