Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Éfésù 1:21-23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

21. Ó gbé e ga ju gbogbo ìsàkóso, àti àṣẹ, àti agbára, àti ilẹ̀ ọba àti gbogbo àpèlé orúkọ tí a lè ti fún mi, kì í ṣe ni ayé yìí nìkan, ṣùgbọ́n ni èyí tí ń bọ̀ pẹ̀lú.

22. Ọlọ́run sì ti fi ohun gbogbo sábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀, ó sì fi í ṣe orí lórí ohun gbogbo fún ìjọ.

23. èyí tí i ṣe ara rẹ̀, ẹ̀kún ẹni tí o kún ohun gbogbo ní gbogbo ọ̀nà.

Ka pipe ipin Éfésù 1