Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Éfésù 1:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ẹ̀yin pẹ̀lú darapọ̀ nínú Kírísítì nígbà tí ẹ̀yin gbọ́ ọ̀rọ̀ òtítọ́ náà àní ìyìnrere ìgbàlà yin. Lẹ́yìn tí ẹ̀yin gbàgbọ́, a lù yín ní òǹtẹ̀ Ẹ̀mí Mímọ́ èyí tí a ti ṣe ìlérí rẹ̀ tẹ́lẹ̀,

Ka pipe ipin Éfésù 1

Wo Éfésù 1:13 ni o tọ