Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Éfésù 1:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pọ́ọ̀lù, Àpósítélì Jésù Kírísítì nípa ìfẹ́ Ọlọ́run,Sí àwọn ènìyàn mímọ́ tí ó wà ní Éfésù, àti sí àwọn olótìtọ́ nínú Kírísíti Jésù:

Ka pipe ipin Éfésù 1

Wo Éfésù 1:1 ni o tọ