Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 9:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti lórí rẹ̀ ni àwọn kérúbù ògo ti i ṣíji bo ìtẹ́ àánú; èyí tí a kò lè sọ̀rọ̀ rẹ̀ nísinsin yìí lọ́kọ̀ọ̀kan;

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 9

Wo Àwọn Hébérù 9:5 ni o tọ