Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 9:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí Kírísítì kò wọ ibi mímọ́ tí a fi ọwọ́ ṣe lọ tí i ṣe àpẹẹrẹ ti òtítọ́; ṣùgbọ́n ó lọ sí ọ̀run páàpáà, nísinsin yìí láti farahàn ní iwájú Ọlọ́run fún wa:

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 9

Wo Àwọn Hébérù 9:24 ni o tọ