Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 9:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí nígbà tí Mósè ti sọ gbogbo àṣẹ nípa ti òfin fún gbogbo àwọn ènìyàn, ó mú ẹ̀jẹ̀ ọmọ màlúù àti ti ewúrẹ́, pẹ̀lú omi, àti òwú òdòdó, àti ewé hísọ́pù ó sì fi wọ́n àti ìwé páàpáà àti gbogbo ènìyàn.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 9

Wo Àwọn Hébérù 9:19 ni o tọ