Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 6:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí nígbà tí Ọlọ́run ṣe ìlérí fún Ábúráhámù, bí kò ti rí ẹni tí ó pọ̀jù òun láti fi búra, ó fi ara rẹ̀ búra, wí pé,

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 6

Wo Àwọn Hébérù 6:13 ni o tọ