Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 5:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni Kírísítì pẹ̀lú kò si ṣe ara rẹ̀ lógo láti jẹ́ olórí àlùfáà; bí kò ṣe ẹni tí o wí fún ún pé,“Ìwọ ni ọmọ mi,lónìn-ín ni mo bi ọ.”

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 5

Wo Àwọn Hébérù 5:5 ni o tọ