Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 5:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí olórí àlùfáà kọ̀ọ̀kan tí a yàn nínú àwọn ènìyàn, ní a fi jẹ nítorí iṣẹ́ ìsìn àwọn ènìyàn sí Ọlọ́run láti máa mú ẹ̀bùn àti ẹbọ wá nítorí ẹ̀ṣẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 5

Wo Àwọn Hébérù 5:1 ni o tọ