Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 4:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti pé, ó yan ọjọ́ kan, ó wí nínú ìwé Dáfídì pé, “Lònìí,” lẹ́yìn ìgbà pípẹ́ bẹ́ẹ̀; bí a tí wí niṣáájú,“Lònì-ín bí ẹ̀yín bá gbọ́ ohùn rẹ̀,ẹ má ṣe sé ọkàn yín le.”

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 4

Wo Àwọn Hébérù 4:7 ni o tọ