Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 3:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbi tí àwọn baba yín ti dán mi wò,tí wọ́n sì rí iṣẹ́ mi ní ogójì ọdún.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 3

Wo Àwọn Hébérù 3:9 ni o tọ