Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 13:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ki ọkàn yín má ṣe fà sí ìfẹ́ owó, ki ohun tí ẹ ní tó yin; nítorí oun tìkararẹ̀ ti wí pé,“Èmi kò jẹ fi ọ́ sílẹ̀,bẹ́ẹ̀ ni èmi kò jẹ kọ̀ ọ́ sílẹ̀.”

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 13

Wo Àwọn Hébérù 13:5 ni o tọ