Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 13:24-25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

24. Ẹ ki gbogbo àwọn tí ń ṣe olórí yín, àti gbogbo àwọn ènìyàn mímọ́. Àwọn tí o ti Ítalì wá ki yín.

25. Kí oore-ọ̀fẹ́ wà pẹ̀lú gbogbo yín. Àmín.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 13