Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 13:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ẹ má ṣe gbàgbé láti máa ṣoore àti láti máa pín funni nítorí irú ẹbọ wọ̀nyí ni inú Ọlọ́run dùn sí jọjọ

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 13

Wo Àwọn Hébérù 13:16 ni o tọ