Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 13:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Kí ìfẹ́ ará o wà títí.

2. Ẹ má ṣe gbàgbé láti máa ṣe àléjò; nítorí pé nípa bẹ́ẹ̀ ni àwọn ẹlòmíràn ṣe àwọn áńgẹ́lì ní àlejò láìmọ̀.

3. Ẹ máa rántí àwọn òǹdè bí ẹni tí a dè pẹ̀lú wọn, àti àwọn tí a ń pọn lójú bí ẹ̀yin tikarayin pẹ̀lú tí ń bẹ nínú ara.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 13