Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 13:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Kí ìfẹ́ ará o wà títí.

2. Ẹ má ṣe gbàgbé láti máa ṣe àléjò; nítorí pé nípa bẹ́ẹ̀ ni àwọn ẹlòmíràn ṣe àwọn áńgẹ́lì ní àlejò láìmọ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 13