Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 12:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ẹ̀yin wá sí òkè Síónì, àti sí ìlú Ọlọ́run alààyè, ti Jerúsálémù ti ọ̀run, àti si ẹgbẹ́ àwọn áńgẹ́lì àìníye,

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 12

Wo Àwọn Hébérù 12:22 ni o tọ