Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 11:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa ìgbàgbọ́ ni ó da àsè ìrekọjá sílẹ̀, àti ìbùwọ́n ẹ̀jẹ̀, kí ẹni tí ń pa àwọn àkọ́bí ọmọ má báa fí ọwọ́ kan wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 11

Wo Àwọn Hébérù 11:28 ni o tọ