Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 11:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa ìgbàgbọ́ ni Jákọ́bù, nígbà ti o ń ku lọ, ó súrre fún àwọn ọmọ Jósẹ́fù ni ìkọ̀ọ̀kan; ó sì sìn ní ìtẹriba lé orí ọ̀pá rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 11

Wo Àwọn Hébérù 11:21 ni o tọ