Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 11:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa ìgbàgbọ́ ni Ábúráhámù, nígbà tí a dan an wò, fi Ísáákì rúbọ: àní òun ẹni tí ó rí ìlérí gba múra tan láti fi ọmọ bíbí rẹ kanṣoṣo rúbọ,

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 11

Wo Àwọn Hébérù 11:17 ni o tọ