Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 11:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ ṣe ti ara ọkùnrin kan jáde, àní ara ẹni tí o dàbí òkú, ọmọ bí ìràwọ̀ ojú ọ̀run lọ́pọ̀lọpọ̀, àti bí ìyanrìn etí òkun láìníyè.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 11

Wo Àwọn Hébérù 11:12 ni o tọ