Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 11:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ǹjẹ́ ìgbàgbọ́ ní ìdánilójú ohun tí o ń réti, ìjeri ohun tí a kò rí.

2. Nítorí nínú rẹ ni àwọn alàgbà (atijọ́) ní ẹ̀rí rere.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 11