Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Tímótíù 4:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa yóò yọ mí kúrò nínú iṣẹ́ bubúrú gbogbo, yóò sì gbà mí dé inú ìjọba rẹ̀; ẹni ti ògo wà fún láé àti láéláé. (Àmín).

Ka pipe ipin 2 Tímótíù 4

Wo 2 Tímótíù 4:18 ni o tọ