Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Tímótíù 4:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà mo pàṣẹ fún ọ níwájú Ọlọ́run, àti Kírísítì Jésù, ẹni tí yóò ṣe ìdájọ́ alààyè àti òkú, àti nítorí ìfarahàn rẹ̀ àti ìjọba rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Tímótíù 4

Wo 2 Tímótíù 4:1 ni o tọ