Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Tẹsalóníkà 3:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní orúkọ Jésù Kirisítì Olúwa wa, àwa pàṣẹ fún-un yín ará, pé kí ẹ yẹra fún gbogbo àwọn arákùnrin yín tí ń ṣe ìmẹ́lẹ́, tí kò sì gbé ní ìbámu pẹ̀lú ẹ̀kọ́ tí ẹ gbà ní ọ̀dọ̀ wa.

Ka pipe ipin 2 Tẹsalóníkà 3

Wo 2 Tẹsalóníkà 3:6 ni o tọ