Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Tẹsalóníkà 3:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àkótan, ará, ẹ máa gbàdúrà fún wa, kí ọ̀rọ̀ Olúwa lè máa tàn káàkiri, kí ó sì jẹ́ èyí tí a bu ọlá fún, gẹ́gẹ́ bí ó ti rí ní ọ̀dọ̀ yín.

Ka pipe ipin 2 Tẹsalóníkà 3

Wo 2 Tẹsalóníkà 3:1 ni o tọ