Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Tẹsalóníkà 2:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní gbogbo ọ̀nà búburú tí a fi ń tan àwọn tí ń ṣègbé jẹ. Wọ́n ṣègbé nítorí wọ́n kọ̀ láti fẹ́ràn òtítọ́ kí wọn sì di ẹni ìgbàlà.

Ka pipe ipin 2 Tẹsalóníkà 2

Wo 2 Tẹsalóníkà 2:10 ni o tọ