Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Tẹsalóníkà 1:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun yóò sì fi ìtura fún ẹ̀yin tí a ti pọ́n lójú àti fún àwa náà pẹ̀lú. Èyí yóò sì se nígbà ìfarahàn Jésù Olúwa láti ọ̀run wá fún wá nínú ọwọ́ iná pẹ̀lú àwọn ańgẹ́lì alágbára.

Ka pipe ipin 2 Tẹsalóníkà 1

Wo 2 Tẹsalóníkà 1:7 ni o tọ