Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Pétérù 3:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa kò fi ìlérí rẹ̀ jáfara, bí àwọn ẹlòmíràn ti ka ìjáfara sí; ṣùgbọ́n ó ń mú sùúrù fún yín nítorí kò fẹ́ kí ẹnikẹ́ni ṣègbé, bí kò ṣe kí gbogbo ènìyàn wá sí ìrònúpìwàdà.

Ka pipe ipin 2 Pétérù 3

Wo 2 Pétérù 3:9 ni o tọ