Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Pétérù 1:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá ṣe aláìní nǹkan wọ̀nyí, kò lè ríran ní òkèèrè ó fọjú, ó sì ti gbàgbé pé a ti wẹ òun nù kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ àtijọ́.

Ka pipe ipin 2 Pétérù 1

Wo 2 Pétérù 1:9 ni o tọ