Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Pétérù 1:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa sì ní ìfẹsẹ̀múlẹ̀ ọ̀rọ̀ àwọn wòlìí dunjúdunjú síi, èyí tí ó yẹ kí ẹ kíyèsí gẹ́gẹ́ bí ìmọ́lẹ̀ tó ń mọ́lẹ̀ níbi tí òkùnkùn gbé wà, títí ilẹ̀ yóò fi mọ́, tí ìràwọ́ òwúrọ̀ yóò sì yọ lọ́kàn yín.

Ka pipe ipin 2 Pétérù 1

Wo 2 Pétérù 1:19 ni o tọ