Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kọ́ríńtì 9:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ìdúró yin lábẹ́ ìdánwò iṣẹ́-ìsìn yìí, wọn yóò yin Ọlọ́run lógo fún ìgbọ́ràn yín ní gbígba ìyìn rere Kírísítì àti nípa ìlawọ́ ìdánwò yín fún wọn àti fún gbogbo ènìyàn.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 9

Wo 2 Kọ́ríńtì 9:13 ni o tọ